• Home
  • Media
  • Languages
  • Web Friends
  • Free Stuff
  • Contact Us

Lessons in:
  • English
  • Français
  • Hausa
  • Yoruba

Sunday Abiodun Owolabi left the world of marketing and finance in 1999 to head West Nigeria Christian College near Abeokuta, Nigeria. He is the Director of WNCC and serves as the Secretary of the school’s Governing Board of Trustees. He has earned a Masters Degree in Missiology and Christian Ministry and a Masters Degree in Church History. Currently, he is working on his doctorate. Owolabi was awarded Pepperdine University’s Distinguished Christian Service Award on May 5, 2010.


Sunday Abiodun Owolabi fi ise ipolowo oja ati eto isuna owo sile ni odun 1999, lati lo gba ise oluwa ni ile ikeko Bibeli, West Nigeria Christian College ni ilu Abeokuta, ni orile ede Nigeria. Nibayi, owun  ni oluko agba, oludari ati akowe igbimo ton se akoso ile eko Bibeli WNCC. O keko gboye imo ijile onipele keji (masters) ninu imo ise iranse ati ipolongo esin kristeni. Bakana ni otun ni imo onipele keji bakana ninu Itan Ijo.  Lowo bayi, Owolabi nsise lori imo eko asekagba (P.hd). Ile eko nla Pepperdine ni ilu Amerika fi ami eye Ogbontarigi  Kristeni tonsise Taakuntakun da Owolabi lola ni ojo karun, osu karun, odun 2010.

More Articles...
  • KINI IGBALA ATI BAWO NI ENIYAN SELE NI ?
feed-image
| Home | Media | Languages | Web Friends | Free Stuff | Contact Us |

Powered by Joomla 1.5.20 | Template modified by WCBC.